Communiversity

Afrikan Language Institute => Yoruba Language Resources => : Samuel Ata Kwabena Ma'at Oct 21, 2017, 06:27 p

: Kí ni ìtúmọ̀ tótó o...-gctid253794
: Samuel Ata Kwabena Ma'at Oct 21, 2017, 06:27 p
Mo kí yín.

Kí ni ìtúmọ̀ "tótó o..." ni èdè òyìnbó?  I know it is a way to show respect to elders, but how does it translate, for example the context:

"Tótó o, àgbà, ó ṣe bíi òwe".

Ẹ ṣeun síwájú.
: Kí ni ìtúmọ̀ tótó o...-gctid254158
: Ɔbenfo Ọbádélé Oct 25, 2017, 07:28 p
Hi Free-quency;253794 wrote: Mo kí yín.

Kí ni ìtúmọ̀ "tótó o..." ni èdè òyìnbó?  I know it is a way to show respect to elders, but how does it translate, for example the context:

"Tótó o, àgbà, ó ṣe bíi òwe".

Ẹ ṣeun síwájú.
Òo,

Kò sí irú ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀yẹn ní èdè/àṣà òyìnbó tí a ní láti sọ nígbà tí a pa òwe níwájú àgbà. Àmọ́, nínú irú gbólóhùn báyìí, a lè sọ pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ni "please excuse me/excuse my language."

Kò tọ́pẹ́ o.
: Kí ni ìtúmọ̀ tótó o...-gctid254457
: Samuel Ata Kwabena Ma'at Oct 27, 2017, 06:59 p
Obadele Kambon;254158 wrote: Òo,

Kò sí irú ọ̀rọ̀ bẹ́ẹ̀yẹn ní èdè/àṣà òyìnbó tí a ní láti sọ nígbà tí a pa òwe níwájú àgbà. Àmọ́, nínú irú gbólóhùn báyìí, a lè sọ pé ìtúmọ̀ rẹ̀ ni "please excuse me/excuse my language."

Kò tọ́pẹ́ o.
Ó dáa. Ò yé mi nísisíyì.

Sent from my iPhone using Abibitumi Kasa mobile app (http://r.tapatalk.com/byo?rid=88213)